Officially released, Osuba by Labisi
The sound “Osuba” is originally owned by Chidinma Ekile, who is currently under the stables of Eezee Concept Global.
Check out this amazing and beautiful melody here below and you will be bless tremendously as you listen to this powerful and spirit lifting sound.
This is a cool sound that worth your playlist. It will definitely bless you.
Stream and download!
LYRICS
Iberu ko si fun mi
Aya o fo mi o
Alade wura
Olorun to ga ju olodo
Talo to o
Ta lo ju o lo baami
Eni to mo wa, oba to mo wa
to mo ohun gbogbo
Olodumare o
Baba mi awimayehun
Ogbigba tin gba ala i lara
Ogbigba tin gba ala i lara
Asoro maye hun
Oni bu ore
………
Oba akoda aye o
Ogbigba tin gba alai lara
Asoro ma ye hun o
[Chorus]
Osuba ba olorun ijaya
Gbani gbani olorun an saya
Eni to le mi mi
Mode
Osuba ba olorun ijaya
Gbani gbani olorun an saya
Eni to le mi mi
Mode
Ogbeni nija keru ba onija
O pin okun niya
Oji oku dide
Iba re ma re SIR
Eleburu ike ni o
Eni to ma
Oba to mo wa
To mo ohun gbogbo
Osuba ba olorun ijaya
Gbani gbani olorun an saya
Eni to le mi mi
E ma ma se o
OFFICIAL VIDEO